1. Oríṣiríṣi àrọko ni ó wà nínú èdè Yorùbá. Àwọn náà ni wonyi
Àrọko oniroyin
Àrọko Aláayè
Àrọko Alapejuwe
Àrọko Alarinyan Jiyàn
Àrọko onisoro gbèsè.
2. Àpẹẹrẹ Àrọko Alarinyan Jiyàn ni wonyi
Ìṣe àgbè dára jù ìṣe dókítà lọ
Ijoba alágbára dára jù ijoba ologun lọ
Ọmọ obìnrin dára jù ọmọ ọkùnrin lọ
Ọmọ wunmi ju owó lọ
Ìgbà ojo dára jù ìgbà èérún lọ