I Onka Yoruba


 
 Onka Yoruba Lati Ori Ookan DeDe Egbeegberun Lona Egberun - Yoruba Numbers from 1 (One) to
 
Naming Numbers as in figure e.g. 3 = Eeta (i.e. Three); 10 = Eewa (i.e. Ten):
 
 Counting Numbers as in calculation, Descriptive Numbers as in position, Yoruba Numbers Counting In 10's Tens, 100's Hundreds And 1,000's Thousands, Yoruba Numbers Counting Up To 1,000,000,000 A Billion

Naming Numbers as in figure e.g. 3 = Eeta (i.e. Three); 10 = Eewa (i.e. Ten):
1 – Ookan
2 – Eeji
3 – Eeta
4 – Eerin
5 – Aarun
6 – Eefa
7 – Eeje
8 – Eejo
9 – Eesan
10 – Eewa
11 – Ookanla
12 – Eejila
13 – Eetala
14 – Eerinla
!5 – Eedogun
16 – Eerindinlogun
17 – Eetadinlogun
18 – Eejidinlogun
19 – Ookandinlogun
20 – Ogun/Okoo
21 – Ookanlelogun
22 – Eejilelogun
23 – Eetalelogun
24 – Eerinlelogun
25 – Eedogbon
26 – Eerindinlogbon
27 – Eetadinlogbon
28 – Eejidinlogbon
29 – Ookandinlogbon
30 – Ogbon
31 – Ookanlelogbon
32 – Eejilelogbon
33 – Eetalelogbon
34 – Eerinlelogbon
35 – Aarundinlogoji
36 – Eerindinlogoji
37 – Eetadinlogoji
38 – Eejidinlogoji
39 – Ookandinlogoji
40 – Ogoji
41 – Ookanlelogoji
42 – Eejilelogoji
43 – Eetalelogoji
44 – Eerinlelogoji
45 – Aarundinlaadota
46 – Eerindinlaadota
47 – Eetadinlaadota
48 – Eejidinlaadota
49 – Ookandinlaadota
50 – Aadota
51 – Ookanlelaadota
52 – Eejilelaadota
53 – Eetalelaadota
54 – Eerinlelaadota
55 – Aarundinlogota
56 – Eerindinlogota
57 – Eetadinlogota
58 – Eejidinlogota
59 – Ookandinlogota
60 – Ogota/Ota
61 – Ookanlelogota
62 – Eejilelogota
63 – Eetalelogota
64 – Eerinlelogota
65 – Aarundinlaadorin
66 – Eerindinlaadorin
67 – Eetadinlaadorin
68 – Eejidinlaadorin
69 – Ookandilaadorin
70 – Aadorin
71 – Ookanlelaadorin
72 – Eejilelaadorin
73 – Eetalelaadorin
74 – Eerinlelaadorin
75 – Aarundinlogorin
76 – Eerindinlogorin
77 – Eetadinlogorin
78 – Eejidinlogorin
79 – Ookandinlogorin
80 – Ogorin/orinn
81 – Ookanlelogorin
82 – Eejilelogorin
83 – Eetalelogorin
84 – Eerinlelogorin
85 – Aarundinlaadorin
86 – Eerindinlaadorin
87 – Eetadinlaadorin
88 – Eejidinlaadorin
89 – Ookandinlaadorin
90 – Aadorin
91 – Ookanlelaadorin
92 – Eejilelaadorin
93 – Eetalelaadorin
94 – Eerinlelaadorin
95 – Aarundinlogorun
96 – Eerindinlogorun
97 – Eetadinlogorun
98 – Eejidinlogorun
99 – Ookandilogorun
100 – Ogorun

Counting Numbers as in calculation e.g. 3 Persons = Eni Meta (i.e. Three Persons); 10 Persons = Eni Mewa (i.e. Ten Persons). The integers of tens (other than ten itself) are counted in naming numbers as nominative e.g. 30 Persons = Ogota Eni (i.e. Thirty Persons); 90 Persons = Eni Aadorun also Aadorun Eni i.e. Ninety Persons; 100 Persons = Ogorun Eni also Eni Ogorun i.e. Hundred Persons:
1 – Meni
2 – Meji
3 – Meta
4 – Merin
5 – Marun
6 – Mefa
7 – Meje
8 – Mejo
9 – Mesan
10 – Mewa
11 – Mokanla
12 – Mejila
13 – Metala
14 – Merinla
!5 – Medogun
16 – Merindinlogun
17 – Metadinlogun
18 – Mejidinlogun
19 – Mokandinlogun
20 – Ogun/Okoo
21 – Mokanlelogun
22 – Mejilelogun
23 – Metalelogun
24 – Merinlelogun
25 – Medogbon
26 – Merindinlogbon
27 – Metadinlogbon
28 – Mejidinlogbon
29 – Mokandinlogbon
30 – Ogbon
31 – Mokanlelogbon
32 – Mejilelogbon
33 – Metalelogbon
34 – Merinlelogbon
35 – Marundinlogoji
36 – Merindinlogoji
37 – Metadinlogoji
38 – Mejidinlogoji
39 – Mokandinlogoji
40 – Ogoji
41 – Mokanlelogoji
42 – Mejilelogoji
43 – Metalelogoji
44 – Merinlelogoji
45 – Marundinlaadota
46 – Merindinlaadota
47 – Metadinlaadota
48 – Mejidinlaadota
49 – Mokandinlaadota
50 – Aadota
51 – Mokanlelaadota
52 – Mejilelaadota
53 – Metalelaadota
54 – Merinlelaadota
55 – Marundinlogota
56 – Merindinlogota
57 – Metadinlogota
58 – Mejidinlogota
59 – Mokandinlogota
60 – Ogota/Ota
61 – Mokanlelogota
62 – Mejilelogota
63 – Metalelogota
64 – Merinlelogota
65 – Marundinlaadorin
66 – Merindinlaadorin
67 – Metadinlaadorin
68 – Mejidinlaadorin
69 – Mokandilaadorin
70 – Aadorin
71 – Mokanlelaadorin
72 – Mejilelaadorin
73 – Metalelaadorin
74 – Merinlelaadorin
75 – Marundinlogorin
76 – Merindinlogorin
77 – Metadinlogorin
78 – Mejidinlogorin
79 – Mokandinlogorin
80 – Ogorin/orinn
81 – Mokanlelogorin
82 – Mejilelogorin
83 – Metalelogorin
84 – Merinlelogorin
85 – Marundinlaadorin
86 – Merindinlaadorin
87 – Metadinlaadorin
88 – Mejidinlaadorin
89 – Mokandinlaadorin
90 – Aadorin
91 – Mokanlelaadorin
92 – Mejilelaadorin
93 – Metalelaadorin
94 – Merinlelaadorin
95 – Marundinlogorun
96 – Merindinlogorun
97 – Metadinlogorun
98 – Mejidinlogorun
99 – Mokandilogorun
100 – Ogorun

Descriptive Numbers as in position e.g. 3rd Third = Eni Iketa, Eni keta i.e. Eni ‘keta, Eni Eketa, Eni Eleketa (i.e. Third Person); 10th Tenth = Eni Ikewa, Eni kewa i.e. Eni ‘kewa, Eni Ekewa, Eni Elekewa (i.e. Tenth Person). The integers of tens (other than ten itself) are described in naming numbers as nominative e.g. 30th Person = Eni Aadota , Eni Ti Aadota (i.e. Thirty Person); 90th Person = Eni Aadorun also Eni Ti Aadorun i.e. Ninetieth Person; 100th Person = Eni Ogorun also Eni Ti Ogorun i.e. Hundredth People:
1st – Ikeni (Kini i.e. ‘kini) / Ekeni / Akoko / Elekeni / Alakoko
2nd – Ikeji (Keji i.e. ‘keji) / Ekeji / Elekeji
2rd – Iketa (Keta i.e. ‘keta) / Eketa / Eleketa
4th – Ikerin (Kerin i.e. ‘kierin) / Ekerin / Elekerin
5th – Ikarun (Karun i.e. ‘karun) / Ekarun / Elekarun
6th – Ikefa (Kefa i.e. ‘kefa) / Ekefa / Elekefa
7th – Ikeje (Keje i.e. ‘kwje) / Ekeje / Elekeje
8th – Ikejo (Kejo i.e. ‘kejo) / Ekejo / Elekejo
9th – Ikesan (Kesan i.e. ‘kesan) / Ekesan / Elekesan
10th – Ikewa (Kewa i.e. ‘kewa) / Ekewa / Elekewa
11th – Ikokanla (Kokanla i.e. ‘kokanla) / Ekokanla / Elekokanla
12th – Ikejila (Kejila i.e. ‘kejila) / Ekejila / Elekejila
13th – Iketala (Ketala i.e. ‘ketala) / Eketala / Eleketala
14th – Ikerinla (Kerinla i.e. ‘kerinla) / Ekerinla / Elekerinla
!5th – Ikedogun (Kedogun i.e. ‘kedogun) / Ekedogun / Elekedogun
16th – Ikerindinlogun (Kerindinlogun i.e. ‘kerindinlogun) / Ekerindinlogun / Elekerindinlogun
17th – Iketadinlogun (Ketadinlogun i.e. ‘ketadinlogun) / Eketadinlogun / Eleketadinlogun
18th – Ikejidinlogun (Kejidinlogun i.e. ‘kejidinlogun) / Ekejidinlogun / Elekejidinlogun
19th – Ikokandinlogun (Kokandinlogun i.e. ‘kokandinlogun) / Ekokandinlogun / Elekokandinlogun
20th – Togun/Tokoo / Okoo / Ti Okoo
21st – Ikokanlelogun / Ekokanlelogun / Elekokanlelogun
22nd – Ikejilelogun / Ekejilelogun / Elekejilelogun
23rd – Iketalelogun / Eketalelogun / Eleketalelogun
24th – Ikerinlelogun / Ekerinlelogun / Elekerinlelogun
25th – Ikedogbon / Ekedogbon / Elekedogbon
26th – Ikerindinlogbon / Ekerindinlogbon / Elekerindinlogbon
27th – Iketadinlogbon / Eketadinlogbon / Eleketadinlogbon
28th – Ikejidinlogbon / Ekejidinlogbon / Elekejidinlogbon
29th – Ikokandinlogbon / Ekokandinlogbon / Elekokandinlogbon
30th – Togbon / Ogbon / Ti Ogbon
31st – Ikokanlelogbon / Ekokanlelogbon / Elekokanlelogbon
32nd – Ikejilelogbon / Ekejilelogbon / Elekejilelogbon
33rd – Iketalelogbon / Eketalelogbon / Eleketalelogbon
34th – Ikerinlelogbon / Ekerinlelogbon / Elekerinlelogbon
35th – Ikarundinlogoji / Ekarundinlogoji / Elekarundinlogoji
36th – Ikerindinlogoji / Ekerindinlogoji / Elekerindinlogoji
37th – Iketadinlogoji / Eketadinlogoji / Eleketadinlogoji
38th – Ikejidinlogoji / Ekejidinlogoji / Elekejidinlogoji
39th – Ikokandinlogoji / Ekokandinlogoji / Elekokandinlogoji
40th – Togoji / Ogoji / Ti Ogoji
41st – Ikokanlelogoji / Ekokanlelogoji / Elekokanlelogoji
42nd – Ikejilelogoji / Ekejilelogoji / Elekejilelogoji
43rd – Iketalelogoji / Eketalelogoji / Eleketalelogoji
44th – Ikerinlelogoji / Ekerinlelogoji / Elekerinlelogoji
45th – Ikarundinlaadota / Ekarundinlaadota / Elekefa
46th – Ikerindinlaadota / Ekerindinlaadota / Elekarundinlaadota
47th – Iketadinlaadota / Eketadinlaadota / Eleketadinlaadota
48th – Ikejidinlaadota / Ekejidinlaadota / Elekejidinlaadota
49th – Ikokandinlaadota / Ekokandinlaadota / Elekokandinlaadota
50th – Taadota / Aadota / Ti Aadota
51st – Ikokanlelaadota / Ekokanlelaadota / Elekokanlelaadota
52nd – Ikejilelaadota / Ekejilelaadota / Elekejilelaadota
53rd – Iketalelaadota / Eketalelaadota / Eleketalelaadota
54th – Ikerinlelaadota / Ekerinlelaadota / Elekerinlelaadota
55th – Ikarundinlogota / Ekarundinlogota / Elekarundinlogota
56th – Ikerindinlogota / Ekerindinlogota / Elekerindinlogota
57th – Iketadinlogota / Eketadinlogota / Eleketadinlogota
58th – Ikejidinlogota / Ekejidinlogota / Elekejidinlogota
59th – Ikokandinlogota / Ekokandinlogota / Elekokandinlogota
60th – Togota/Tota / Ota / Ti Ota
61st – Ikokanlelogota / Ekokanlelogota / Elekokanlelogota
62nd – Ikejilelogota / Ekejilelogota / Elekejilelogota
63rd – Iketalelogota / Eketalelogota / Eleketalelogota
64th – Ikerinlelogota / Ekerinlelogota / Elekerinlelogota
65th – Ikarundinlaadorin / Ekarundinlaadorin / Elekarundinlaadorin
66th – Ikerindinlaadorin / Ekerindinlaadorin / Elekerindinlaadorin
67th – Iketadinlaadorin / Eketadinlaadorin / Eleketadinlaadorin
68th – Ikejidinlaadorin / Ekejidinlaadorin / Elekejidinlaadorin
69th – Ikokandilaadorin / Ekokandilaadorin / Elekokandilaadorin
70th – Taadorin / Aadorin / Ti Aadorin
71st – Ikokanlelaadorin / Ekokanlelaadorin / Elekokanlelaadorin
72nd – Ikejilelaadorin / Ekejilelaadorin / Elekejilelaadorin
73rd – Iketalelaadorin / Eketalelaadorin / Eleketalelaadorin
74th – Ikerinlelaadorin / Ekerinlelaadorin / Elekerinlelaadorin
75th – Ikarundinlogorin / Ekarundinlogorin / Elekarundinlogorin
76th – Ikerindinlogorin / Ekerindinlogorin / Elekerindinlogorin
77th – Iketadinlogorin / Eketadinlogorin / Eleketadinlogorin
78th – Ikejidinlogorin / Ekejidinlogorin / Elekejidinlogorin
79th – Ikokandinlogorin / Ekokandinlogorin / Elekokandinlogorin
80th – Togorin/Toorin / Oorin / Ti Oorin
81st – Ikokanlelogorin / Ekokanlelogorin / Elekokanlelogorin
82nd – Ikejilelogorin / Ekejilelogorin / Elekejilelogorin
83rd – Iketalelogorin / Eketalelogorin / Eleketalelogorin
84th – Ikerinlelogorin / Ekerinlelogorin / Elekerinlelogorin
85th – Ikarundinlaadorin / Ekarundinlaadorin / Elekarundinlaadorin
86th – Ikerindinlaadorin / Ekerindinlaadorin / Elekerindinlaadorin
87th – Iketadinlaadorin / Eketadinlaadorin / Eleketadinlaadorin
88th – Ikejidinlaadorin / Ekejidinlaadorin / Elekejidinlaadorin
89th – Ikokandinlaadorin / Ekokandinlaadorin / Elekokandinlaadorin
90th – Taadorin / Aadorin / Ti Aadorin
91st – Ikokanlelaadorin / Ekokanlelaadorin / Elekokanlelaadorin
92nd – Ikejilelaadorin / Ekejilelaadorin / Elekejilelaadorin
93rd – Iketalelaadorin / Eketalelaadorin / Eleketalelaadorin
94th – Ikerinlelaadorin / Ekerinlelaadorin / Elekerinlelaadorin
95th – Ikarundinlogorun / Ekarundinlogorun / Elekarundinlogorun
96th – Ikerindinlogorun / Ekerindinlogorun / Elekerindinlogorun
97th – Iketadinlogorun / Eketadinlogorun / Eleketadinlogorun
98th – Ikejidinlogorun / Ekejidinlogorun / Elekejidinlogorun
99th – Ikokandilogorun / Ekokandilogorun / Elekokandilogorun
100th – Togorun / Ogorun / Ti Ogorun

Yoruba Numbers Counting In 10's Tens, 100's Hundreds And 1,000's Thousands
20 – Ogun
30 – Ogbon
40 – Ogoji (i.e. Ogun Meji = 2 Twenties)
50 – Aadota
60 – Ogota (i.e. Ogun Meta = 3 Twenties)
70 – Aadorin
80 – Ogorin (i.e. Ogun Merin = 4 Twenties)
90 – Aadorun
90 – Ogorun (i.e. Ogun Marun = 5 Twenties)
110 – Aadofa
120 – Ogofa (i.e. Ogun Mefa = 6 Twenties)
130 – Aadoje
140 – Ogoje (i.e. Ogun Meje = 7 Twenties)
150 – Aadojo
160 – Ogojo (i.e. Ogun Mejo = 8 Twenties)
170 – Aadosan
180 – Ogosan (i.e. Ogun Mesan = 9 Twenties)
190 – Eedingba / Eedogbo (i.e. Eewa Din Ni Igba = 200 Minus 10)
200 – Igba (i.e. Ogun Marun [Egba viz Eeji Eewa Ni Mewa) = 2 Ten By Ten)
300 – Orundin-Ni-Rinho (i.e. Ogorun Din Irin-ho = 100 Minus 400)
400 – Irinhun / Erinho / Eriwo (i.e. Erin Ogorun = 4 Five Twenties)
500 – Orundinlegbeta (i.e. Ogorun Din Egbeta = 100 Minus 600)
600 – Egbeta (i.e. Igba Meta = 3 Two Hundreds)
700 – Orundinlegberin (i.e. Ogorun Din Egberin = 100 Minus 800)
800 – Egberin (i.e. Igba Merin = 4 Two Hundreds)
900 – Orundinlegberun (i.e. Ogorun Din Egberun = 100 Minus 1,000)
1,000 – Egberun (i.e. Igba Marun = 5 Two Hundreds)
1,100 – Orundinlegbefe (i.e. Ogorun Din Egbefa = 100 Minus 1,200)
1,200 – Egbefa (i.e. Igba Mefa = 6 Two Hundreds)
1,300 – Orundinlegbeje (i.e. Ogorun Din Egbeje = 100 Minus 1,400)
1,400 – Egbeje (i.e. Igba Meje = 7 Two Hundreds)
1,500 – Orundinlegbejo (i.e. Ogorun Din Egbejo = 100 Minus 1,600)
1,600 – Egbejo (i.e. Igba Mejo = 8 Two Hundreds)
1,700 – Orundinlegbesan (i.e. Ogorun Din Egbesan = 100 Minus 1,800)
1,800 – Egbesan (i.e. Igba Mesan = 9 Two Hundreds)
1,900 – Orundinlegbejo (i.e. Ogorun Din Egbewa = 100 Minus 2,000)
2,000 – Egbewa (i.e. Igba Mewa = 10 Two Hundreds)
2,100 – Orundinlegbokanla (i.e. Ogorun Din Egbokanla = 100 Minus 2,200)
2,200 – Egbokanla (i.e. Igba Mokanla = 11 Two Hundreds)
2,300 – Orundinlegbejila (i.e. Ogorun Din Egbejila = 100 Minus 2,400)
2,400 – Egbejila (i.e. Igba Mejila = 12 Two Hundreds)
2,500 – Orundinlegbetala (i.e. Ogorun Din Egbejila = 100 Minus 2,600)
2,600 – Egbetala (i.e. Igba Metala = 13 Two Hundreds)
2,700 – Orundinlegberinla (i.e. Ogorun Din Egberinla = 100 Minus 2,800)
2,800 – Egberinla (i.e. Igba Merinla = 14 Two Hundreds)
2,900 – Orundinlegbedogun (i.e. Ogorun Din Egbeedogun = 100 Minus 3,000)
3,000 – Egbeedogun (i.e. Igba Meedogun = 15 Two Hundreds)
3,100 – Orundinlegberindinlogun (i.e. Ogorun Din Egberindinlogun = 100 Minus 3,200)
3,200 – Egberindinlogun (i.e. Igba Merindinlogun = 16 Two Hundreds)
3,300 – Orundinlegbetadinlogun (i.e. Ogorun Din Egbetadinlogun = 100 Minus 3,400)
3,400 – Egbetadinlogun (i.e. Igba Metadinlogun = 17 Two Hundreds)
3,500 – Orundinlegbejidinlogun (i.e. Ogorun Din Egbejidinlogun = 100 Minus 3,600)
3,600 – Egbejidinlogun (i.e. Igba Mejidinlogun = 18 Two Hundreds)
3,700 – Orundinlegbokandinlogun (i.e. Ogorun Din Egbonkandinlogun = 100 Minus 3,800)
3,800 – Egbokandinlogun (i.e. Igba Mokandinlogun = 19 Two Hundreds)
3,900 – Orundinloko-ho (i.e. Ogorun Din Oko-ho = 100 Minus 4,000)
4,000 – Okohun / Okoho / Oko-hun / Oko-o (i.e. Ogorun Ati Ogorun Ogun = 100 and 100 Twenty Times)
4,100 – Orundinlegbokanlelogun (i.e. Ogorun Din Egbokanlelogun = 100 Minus 4,200)
4,200 – Egbokanlelogun (i.e. Igba Mokanlelogun = 21 Two Hundreds)
4,300 – Orundinlegbejilelogun (i.e. Ogorun Din Egbejilelogun = 100 Minus 4,400)
4,400 – Egbejilelogun (i.e. Igba Mejilelogun = 22 Two Hundreds)
4,500 – Orundinlegbetalelogun (i.e. Ogorun Din Egbetalelogun = 100 Minus 4,600)
4,600 – Egbetalelogun (i.e. Igba Metalelogun = 23 Two Hundreds)
4,700 – Orundinlegberinlelogun (i.e. Ogorun Din Egberinlelogun = 100 Minus 4,800)
4,800 – Egberinlelogun (i.e. Igba Merinlelogun = 24 Two Hundreds)
4,900 – Orundinlegberinlelogun (i.e. Ogorun Din Egberinlelogun = 100 Minus 5,000)
5,000 – Egbeedogbon (i.e. Igba Meedogbon (Igba Marundinlogbon) = 25 Two Hundreds)
5,100 – Orundinlegberinlelogun (i.e. Ogorun Din Egberinlelogun = 100 Minus 5,200)
5,200 – Egberindinlogbon (i.e. Igba Merindinlogbon = 26 Two Hundreds)
5,300 – Orundinlegbetadinlogbon (i.e. Ogorun Din Egbetadinlogbon = 100 Minus 5,400)
5,400 – Egbetadinlogbon (i.e. Igba Metadinlogbon = 27 Two Hundreds)
5,500 – Orundinlegbejidinlogbon (i.e. Ogorun Din Egbejidinlogbon = 100 Minus 5,600)
5,600 – Egbejidinlogbon (i.e. Igba Mejidinlogbon = 28 Two Hundreds)
5,700 – Orundinlegbokandinlogbon (i.e. Ogorun Din Egbokandinlogbon = 100 Minus 5,600)
5,800 – Egbokandinlogbon (i.e. Igba Mokandinlogbon = 29 Two Hundreds)
5,900 – Orundinlegbokandinlogbon (i.e. Ogorun Din Egbokandinlogbon = 100 Minus 5,600)
6,000 – Igbagbon (i.e. Igba Ogbon = 30 Two Hundreds)
6,100 – Orunlegbagbon (i.e. Ogorun Le Igbagbon = 100 Plus 6,000)
6,200 – Igbakanlegbagbon (i.e. Igba Kan Le Igbagbon = 200 Plus 6,000)
6,300 – Orundingbejilegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbejilegbagbon = 100 Minus 6,400)
6,400 – Igbejilegbagbon (i.e. Igba Meji Le Igbejilegbagbon = 400 Plus 6,000)
6,500 – Orundingbetalegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbetalegbagbon = 100 Minus 6,600)
6,600 – Igbetalegbagbon (i.e. Igba Meji Le Igbagbon = 600 Plus 6,000)
6,700 – Orundingberinlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igberinlegbagbon = 100 Minus 6,800)
6,800 – Igberinlegbagbon (i.e. Igba Merin Le Igbagbon = 800 Plus 6,000)
6,900 – Orundingbarunlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbarunlegbagbon = 100 Minus 7,000)
7,000 – Igbarunlegbagbon (i.e. Igba Marun Le Igbagbon = 1,000 Plus 6,000)
7,100 – Orundingbefalegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbefalegbagbon = 100 Minus 3,200)
7,200 – Igbefalegbagbon (i.e. Igba Mefa Le Igbagbon = 1,200 Plus 6,000)
7,300 – Orundingbejelegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbejelegbagbon = 100 Minus 3,400)
7,400 – Igbejelegbagbon (i.e. Igba Meje Le Igbagbon = 1,400 Plus 6,000)
7,500 – Orundingbejolegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbejolegbagbon = 100 Minus 7,600)
7,600 – Igbejolegbagbon (i.e. Igba Mejo Le Igbagbon = 1,200 Plus 6,000)
7,700 – Orundingbesanlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbesanlegbagbon = 100 Minus 7,800)
7,800 – Igbesanlegbagbon (i.e. Igba Mesan Le Igbagbon = 1,200 Plus 6,000)
7,900 – Orundingbewalegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbewalegbagbon = 100 Minus 4,000)
8,000 – Igbewalegbagbon (i.e. Igba Mewa Le Igbagbon = 1,200 Plus 6,000)
8,100 – Orundingbonkanlalelogunlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbonkanlalelogun Le Igbagbon = 100 Minus 8,200)
8,200 – Igbonkanlalelogunlegbagbon (i.e. Igba Mokanlalelogun Le Igbagbon = 200 x 21 Plus 6,000)
8,300 – Ogbejilalelogunlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbejilalelogun Le Igbagbon = 100 Minus 3,800)
8,400 – Igbejilalelogunlegbagbon (i.e. Igba Mejila Lelogun Le Igbagbon = 200 x 22 Plus 6,000)
8,500 – Orundingbetalalelogunlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igbetalalelogun Le Igbagbon = 100 Minus 3,800)
8,600 – Igbetalalelogunlegbagbon (i.e. Igba Metala Le Igbagbon = 200 x 23 Plus 6,000)
8,700 – Orundingberindinlogunlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igberinla Lelogun Le Igbagbon = 100 Minus 3,800)
8,800 – Igberinlelogunlegbagbon (i.e. Igba Merinla Lelogun Le Igbagbonn = 200 x 24 Plus 6,000)
8,900 – Orundingbeedogbonlegbagbon (i.e. Ogorun Din Egbeedogbon Le Igbagbon = 100 Minus 9,000)
9,000 – Igbeedogbonlegbagbon (i.e. Egbeedogbon Le Igbagbon = 200 x 25 Plus 6,000)
9,100 – Orundingberindinlogbonlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igba Merindinlogbon Le Igbagbon = 100 Minus 9,200)
9,200 – Igberindinlogbonlegbagbon (i.e. Igba Merindinlogbon Le Igbagbon = 200 x 26 Plus 6,000)
9,300 – Orundingbetadinlogbonlegbagbon (i.e. Ogorun Din Egbonkandinlogun = 100 Minus 9,400)
9,400 – Igbetadinlogbonlegbagbon (i.e. Igba Metadinlogbon Le Igbagbon = 200 x 27 Plus 6,000)
9,500 – Orundingbejidinlogbonlegbagbon (i.e. Ogorun Din Egbonkandinlogun = 100 Minus 9,600)
9,600 – Igbejidinlogbonlegbagbon (i.e. Igba Mejidinlogbon Le Igbagbon = 200 x 28 Plus 6,000)
9,700 – Orundingbokandinlogbonlegbagbon (i.e. Ogorun Din Igba Mokandinlogbon Le Igbagbon = 100 Minus 9,800)
9,800 – Igbokandinlogbonlegbagbon (i.e. Igba Mokandinlogbon Le Igbagbon = 200 x 29 Plus 6,000)
9,900 – Orundingberunmewa (i.e. Ogorun Din Egberunmewa = 100 Minus 10,000)
10,000 – Egberunmewa (i.e. Egberun Mewa = 10 One Thousands)

Yoruba Numbers Counting Up To 1,000,000,000 A Billion
1,000 – Egberun (Kan) (i.e. Egberun (Kan) = One Thousand)
10,000 – Egberunmewa (i.e. Egberun Mewa = 10 Thousands)
100,000 – Egberunlogorun (i.e. Egberun Ni Ogorun = 100 Thousands)
200,000 – Egberunlogorunmeji (i.e. Egberun Ni Ogorun Meji = 200 Thousands)
300,000 – Egberunlogorunmeta (i.e. Egberun Ni Ogorun Meji = 300 Thousands)
400,000 – Egberunlogorunmerin (i.e. Egberun Ni Ogorun Meji = 400 Thousands)
500,000 – Egberunlogorunmarun (i.e. Egberun Ni Ogorun Meji = 500 Thousands)
600,000 – Egberunlogorunmefa (i.e. Egberun Ni Ogorun Meji = 600 Thousands)
700,000 – Egberunlogorunmeje (i.e. Egberun Ni Ogorun Meji = 700 Thousands)
800,000 – Egberunlogorunmejo (i.e. Egberun Ni Ogorun Meji = 800 Thousands)
900,000 – Egberunlogorunmesan (i.e. Egberun Ni Ogorun Meji = 900 Thousands)
1,000,000 – Egbeegberun (i.e. Egberun Ni Egberun = 1,000 Thousands [One Million])
1,000,000,000 – Egbeegberun Lona Egberun (i.e. Egbeegberun Ni Egberun = 1,000,000 Thousands [One Billion])

  
Akole: Imo Ofin-Olohun - Awon Ibeere Ati Idahun

No comments