Followers

Follow by Email

Asegbolu Matched Content

Join us on Facebook

Naija we hail oooo Una no dey fail oooo even when the country they wail lli oooo

Powered by Blogger.
Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...
Email Newsletter

Subscribe to our newsletter to get the latest updates to your inbox. ;-)

Your email address is safe with us!

ENI OKAN MI. (MY DEAREST)

ENI OKAN MI. (MY DEAREST)

Ó yá, eni okan mi,
té'wo àdúra:
Mo gba àdúrà yi fún o ati fun gbogbo idile re ni iyoku odun 2016 yi wípé l'ónìí àti l'ójó gbogbo...
Ojú kò  ní tì e. 
Ayé kò ní yò e.
Olórun kò ní gba ògo re fún elòmíràn láéláé.
Igbá ilé re kò ní fó.
Aso ìbora re kò ní fà ya.
Ayé kò ní da àbàwón sí aso re.
Àgbá omi re kò ní gbe.
Kókóró ayò re kò ní bá omi lo.
Bí o bá n taá, á máa jó.
Bí o bá n lùú, á máa dún.
Abéré olóore re kò ni bó s'ómi.
Omo aráyé kò ní fi ire tìre se àpínle.
Bí ó ti wù kí ilé ìwòsån dára tó, oò nì fi ibe se ibùgbé.
Bí ó ti wù kí aso èwòn l'éwà tó, oò ní bá won wò ní'bè .
Won o ní fi èjè re se ìrúbo.
Ohun tí omo aráyé kò  fi pamó sí o l'ówó, won kò ní bèèrè re l'ówóo re.
Omo aráyé kò ní fi egba fún o l'óúnje.
Bí ó ti wù kí àná ati òní re dára tó, òla re yóó l'éwà ju gbogbo won lo.
Orí re kò ní burú, èdá re kò ní gb'àbòdè
Gbogbo ibití elégbé re bá ti n ná owó, o kò ní bá won ná aájò nibe.
Oò ní se àsetì.
Wa á lu àlùyo.
Omo aráyé kò ní bó bàtà òfò si enu ònà iléè re.....Aaaamin
l'agbara Eledumare.
Asiko yi a tuwa lara
Ireti wa ko ni ja s'ofo.
Gbogbo igi ti elegbede ba fowo lu didun lo ndun.. Gbogbo adawole re yo yori si rere.
Gbogbo owo ti ogede ba na soke, ara re lo nfi lu kehin. Enikeni, edakeda, eeyan-keeyan ti abi ninu obinrin, abi ti a fabe gbebi e, to ba ro ibi ro e, ko fi ori ara re gbe.
Ilekun aanu ko ni ti mo e.
Ibukun ati alafia ti aye kole jakule ni yoo je ipin re.
Oju owo ko ni pon e.
Oro re yo dayo.
Emi wa a se opolopo Odun laye. Amin. 2016 odun ayo ni Olorun yio $e ooo. Owo wa a to eti,okan wa abale o. Oro jade, Ase gun.☀ God asked me to tell you: That everything will be alright from now on... You're to be victorious and will achieve all your goals. Today, God will visit your home. On his way out, He will take all your problems with Him. Do me a favour. Trust God and share this message with ten friends of yours , do not ignore. Do it and wait for 10 minutes, you will receive a very nice news. It costs nothing to share. Faith can move mountains. Try it. It is well. (Amin).

No comments:

Post a Comment

About

Add Your Gadget Here

Entertainment

Latest News

Entertainment

Subscribe Via Email

Subscribe to our newsletter to get the latest updates to your inbox. ;-)

Your email address is safe with us!

(C) Copyright by Naija Google Blogger
Wordpress Theme by QualityWP | Conveted to Blogger Template by ThemeLib.com

Search This Blog

Pages

Total Pageviews

About Me

author
Learn More →

Search Box

ENI OKAN MI. (MY DEAREST)

ENI OKAN MI. (MY DEAREST)

Ó yá, eni okan mi,
té'wo àdúra:
Mo gba àdúrà yi fún o ati fun gbogbo idile re ni iyoku odun 2016 yi wípé l'ónìí àti l'ójó gbogbo...
Ojú kò  ní tì e. 
Ayé kò ní yò e.
Olórun kò ní gba ògo re fún elòmíràn láéláé.
Igbá ilé re kò ní fó.
Aso ìbora re kò ní fà ya.
Ayé kò ní da àbàwón sí aso re.
Àgbá omi re kò ní gbe.
Kókóró ayò re kò ní bá omi lo.
Bí o bá n taá, á máa jó.
Bí o bá n lùú, á máa dún.
Abéré olóore re kò ni bó s'ómi.
Omo aráyé kò ní fi ire tìre se àpínle.
Bí ó ti wù kí ilé ìwòsån dára tó, oò nì fi ibe se ibùgbé.
Bí ó ti wù kí aso èwòn l'éwà tó, oò ní bá won wò ní'bè .
Won o ní fi èjè re se ìrúbo.
Ohun tí omo aráyé kò  fi pamó sí o l'ówó, won kò ní bèèrè re l'ówóo re.
Omo aráyé kò ní fi egba fún o l'óúnje.
Bí ó ti wù kí àná ati òní re dára tó, òla re yóó l'éwà ju gbogbo won lo.
Orí re kò ní burú, èdá re kò ní gb'àbòdè
Gbogbo ibití elégbé re bá ti n ná owó, o kò ní bá won ná aájò nibe.
Oò ní se àsetì.
Wa á lu àlùyo.
Omo aráyé kò ní bó bàtà òfò si enu ònà iléè re.....Aaaamin
l'agbara Eledumare.
Asiko yi a tuwa lara
Ireti wa ko ni ja s'ofo.
Gbogbo igi ti elegbede ba fowo lu didun lo ndun.. Gbogbo adawole re yo yori si rere.
Gbogbo owo ti ogede ba na soke, ara re lo nfi lu kehin. Enikeni, edakeda, eeyan-keeyan ti abi ninu obinrin, abi ti a fabe gbebi e, to ba ro ibi ro e, ko fi ori ara re gbe.
Ilekun aanu ko ni ti mo e.
Ibukun ati alafia ti aye kole jakule ni yoo je ipin re.
Oju owo ko ni pon e.
Oro re yo dayo.
Emi wa a se opolopo Odun laye. Amin. 2016 odun ayo ni Olorun yio $e ooo. Owo wa a to eti,okan wa abale o. Oro jade, Ase gun.☀ God asked me to tell you: That everything will be alright from now on... You're to be victorious and will achieve all your goals. Today, God will visit your home. On his way out, He will take all your problems with Him. Do me a favour. Trust God and share this message with ten friends of yours , do not ignore. Do it and wait for 10 minutes, you will receive a very nice news. It costs nothing to share. Faith can move mountains. Try it. It is well. (Amin).

Share on Google Plus

About Naija Google Blogger

This is a short description in the author block about the author. You edit it by entering text in the "Biographical Info" field in the user admin panel.

0 comments:

Post a Comment