Ìṣe dá Ọ̀rọ̀ Orúkọ

      1. Orisirisi ona ni a lè gbà láti s'eda oro orúkọ. Nípa lílo afọmọ ibere (ai) àti (òní)
Bíi àpẹẹrẹ

1. Ai + ku = aiku
2. Ai + lowo = àìlọ́wọ̀
3. Ai + jẹun = aijeun
4. Ai + sise = àṣìṣe
Áì + gbagbọ = aigbagbo

      2. Ona miran ti a lè tún lè gbà s'eda oro orúkọ ni nípa lílo afọmọ ìbéèrè {oni}
  Bíi àpẹẹrẹ
1. Oni + ata = alata
2. Oni + aso = alaso
3. Òní + aya  = aláya
4. Òní + ọkọ  = okoko
5. Òní + ilé    = onílé

      3.  A tun le s'eda oro nípa lílo afọmọ àárín (ki)  nípa sísọ oro orúkọ mejo papọ
Bíi àpẹẹrẹ
1. Ile + ki + ilé = ilekile
2. Ise + kí + ìṣe = isekise
3. Ọmọ + kí + ọmọ = omokomo
4 . ilé + kí + ilé  = ilekile

Share on Google Plus

About Olusegun Bolujo

This is a short description in the author block about the author. You edit it by entering text in the "Biographical Info" field in the user admin panel.