Oge Ṣíṣe Nílé Yoruba

         Oge sise je okan ninu awon àṣà ilé wa. Orisirisi ó náà ni a máa ngba láti tún ẹwà ara wa ṣeé. Bí àpẹẹrẹ 

1. Osun kíkún 

2. Laali l'île 

3. Tiro l'île 

4. Etí lílu 

5. Eyin pípa 

6. Irun dídì àti orí fífà 

7. Aṣọ wíwò 

8. Fífín kolo/ ara fífín 

9. Ìlà kiko 1. Osun kíkún : Àwa Yoruba ni a ní àṣà Osun kíkún nii ikawo.  Osun pupa. Inú ìgbà ni o máa nwa. A man kún Osun níbi isomoloruko tàbí ìgbéyàwó. Ìdí nìyẹn tí a máa fii sọ wípé a ó fi owó kan Osun fii paa ọmọ lára. Tàbí ìyàwó elese Osun tí ó lon ilé ọkọ 

2. Laali l'île : Àwọn Hausa ni o ni Laali lile láti ìbéèrè pẹpẹ. A kọọ àṣà Laali l'île láti ọ̀dọ̀ àwọn Hausa. Èwe igi ni a mo gege bí èwe igi Laali. A o gun èwe igi yii. A o fi kan-un sii, leyin náà a ó tó sì ẹgbẹ́ ẹsẹ wá. Àwọn miran máa ń di adisa mọọ fún òjò mẹta kii ó má bàa tètè parée. 

3. Tiro l'île  Tiro l'île dára púpò. Àti ọkùnrin àti obìnrin ni o náà leè tiro. Àwọn ìyá wàá feran láti máa kún tiro soju ọmọ titun tí a sese bíi.. 
Ebu dúdú ni a man fii see tiro. Pelu ọ̀pá tiro tíì a man fi kún soju 


Tiro l'île man kò idoti kúrò nínú ojú. Ó sii Man jeki a rìn rán daradara 

4 : Etí lílu.  Àwọn obìnrin ni o ma luti. Wọn máa luti mejeji láti kó yẹtí ṣe tí. 


5. Eyin Pupa.  Àti ọkùnrin àti obìnrin ni o maa npa eyín ni ile Yoruba.  ni ile Yoruba. 

--

No comments