WpMag

Search This Blog

Friday, November 3, 2017

Iseda Ọ̀rọ̀ Orúkọ

Ìṣe dá Ọ̀rọ̀ Orúkọ
1)  Àwa Yoruba s'eda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere, afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe àti àpe tún pe kíkún

2) Àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda nípa lílo afọmọ ibere :ai àti òní.
Fún àpẹẹrẹ 
Ai 
Kú 
Aiku 

Ai
Jẹun 
Aijeun 

Ai
Lowo 
Ailowo 

Ai 
Là 
Aila 

Ai 
Sun
Aisun 

Ai 
Gbogbo 
Aigbagbo 


3) iseda oro orúkọ nípa lílo afọmọ ibere òní àti orúkọ
Fún àpẹẹrẹ
Oni
Isu
Onisu

Oni
Ile
Onílé 

Oni 
Ata
Alata 

Oni
Omo
Olomo 

Oni
Aya 
Alaya 

Oni 
Oko
Oloko 


4) Iseda ọ̀rọ̀ orúkọ nípa lílo afọmọ àárín àti oro orúkọ méjì èyí ti aranmo máa ń ṣẹlẹ̀ nibe
Fún àpẹẹrẹ
Oro orúkọ 
Afọmọ àárín 
Ọ̀rọ̀ orúkọ 
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda 

Ìṣe 
Ki
Ise
Isekise 

Ilé 
Ki
Ilé 
Ilekile 

Aṣọ 
Ki
Aso
Asokaso 

Ọmọ 
Ki
Omo
Omokomo 

Aya 
Ki
Aya
Ayakaya 


5) iseda oro orúkọ nípa pípa ọ̀rọ̀ orúkọ méjì pò láti di oro orúkọ kan.
Fún àpẹẹrẹ
Ọ̀rọ̀ orúkọ 
Ọ̀rọ̀ orúkọ 
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda 

Etí 
Odò 
Etido 

Eti
Ike
etile 

Eti
Okun
Etíkun 

Ojú 
Ode 
Ojúde 

Ọmọ 
Ọkùnrin 
Ọmọkùnrin 


6) iseda oro orúkọ èyí tí aranmo máa wáyé
Fún àpẹẹrẹ
Ọ̀rọ̀ orúkọ 
Ọ̀rọ̀ orúkọ 
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda 

Ilé 
Ìwé
Iléèwé 

Ilé 
Ìṣe 
Ileese 

Ara 
Oko
Arooko 

Àyà 
Ọba 
Ayaaba 

Ìyá 
Ègbé 
Iyaegbe 

Ara
Ilé 
Araale 


7) iseda oro orúkọ nípa lílo apetunpe oro ìṣe àti oro ìṣe láti di ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda
Fún àpẹẹrẹ

Àpólà oro ìṣe 
Àpólà oro ìṣe 
Ọ̀rọ̀ orúkọ tí a s'eda 

Jagun 
Jagun 
Jagunjagun 

Wole 
Wole 
Wolewole 

Kólé 
Kólé 
Kokekole 

Kọrin 
Kọrin 
Korinkorin 

Pana 
Pana 
Panapana 

Gbomo 
Gbomo 
Gbomogbomo 

Tafa 
Tafa 
Tafatafa 

Lagi 
Lagi 
Lagilagi 

Search This Blog

Pages