1st Term Examination Yoruba 2018 /2019 Academic Year

ISLAND BUILDERS BAPTIST SCHOOL
(NURSERY & PRIMARY)
15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.

FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 1                      SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………...

 1. FI LETA TI OYE DI AWON ALAFO WONYII
A      ________    D    ________       Ę       ________    G    _________
H    _________    J    ________       L      ________    N    _________
Ǫ   ________     R    ________      Ș    ________       U      _________    Y   

 1. DI AWON ALAFO WONYII PELU LETA TI O YE  
 1. A d ____      (e   ,    p)
 2. E ____ e         (k   ,    w)
 3. ____ j a         (E  ,    M)
 4. I g ____         (s  ,    o)
 5. O ____ o        (K   ,    T)
 1. KINI ORUKO AWON AWORAN WONYII:
 1.                 (Ade, Ile)
 2.                 (Ododo, Ewe)
 3.                 (Eja, Akan)
 4.                 (Garawa, Igo)
 5.                 (Owo, Ade)


 1. MELO NIL ETA EDE YORUBA
 1. Melo nil eta ede Yoruba lapapo (a) marundinlogbon     (b) mejidinlogun
 2. Melo ni iro faweli airanmupe ede Yoruba (a) mewa     (b) meje
 3. Melo ni iro faweli aranmupe ede Yoruba (a) marun-un     (b) mejo
 4. Melo ni awon konsonanti ede Yoruba (a) mejila    (b) mejidinlogun
 5. Ewo ni konsonanti aranmupe ninu awon wonyii  (a) p       (b) n    (c) s

ISLAND BUILDERS BAPTIST SCHOOL
(NURSERY & PRIMARY)
15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.

FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 2                      SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………...

ORIN AKOMONIWA: OMO RERE
 1. Omo rere kii ___________    (a) puro    (b) s’ore
 2. Omo rere kii ___________    (a) sun    (b) sole
 3. Omo rere kii ___________    (a) jale    (b) woso
 4. Omo rere kii ___________    (a) ponmi    (b) seke
 5. Omo rere kii ___________    (a) ja        (b) gbadura

IWA OMOLUABI: ITOJU ATI OORE SISE
1.) _________ nse baba Aina (a) aisan     (b) arun
2.) ____________ wa kii. (a) Yemi    (b) Aina
3.) ___________________ fee ro (a) ojo    (b) omi  
4.) Iya _________________________ sa awon aso re si ita (a) Kola (b) Ade
5.) ________________ nba ka awon aso naa (a) Yemi (b) Tola

IROYIN ATI ASOGBA
 1. Ile-eko mi dara, tani o nsoro yii? (a) Tunde     (b) Alaba
 2. Bee ni, sugbon ko dara to ile-eko ti wa, tani o nsoro yii? (a) Alaba     (b) Tunde
 3. Wo o bi ododo se po yi kilaasi mi ka, tani o nsoro yii? (a) Tunde     (b) Alaba
 4. Igi ti o lewa po ni ile-eko temi ju tire lo, tani o nsoro yii  (a) Tunde     (b) Alaba
 5. Wo maluu ti baba mi ra, tani o nsoro yii? (a) Alaba     (b) Tunde

AROFO IMOTOTO
 1. Fo ______________ re bi o baji (a) eyin (b) ese
 2. Gba __________________ re pelu (a) ori (b) ayika
 3. Ge _______________ re lasiko to ye (a) irun    (b) imu
 4. ______________ ti ngbe abe eekannaa ko kere  (a) aisan   (b) arun
 5. ____________ buburu jinna si o tefe (a) arun    (b) kaisan
ISLAND BUILDERS BAPTIST SCHOOL
(NURSERY & PRIMARY)
15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.

FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 3                      SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………...

EWI: IBAWI
 1. Arofo yii nba omo ________________ wi (a) ile-eko (b) ile-ise
 2. __________ to gbo baa wi ni deni _________ leyin ola (a) omo giga (b) aya rere
 3. Omo to gbo ____________ nii fi __________ sese rin  (a) aya keke (b) omo moto
 4. Eko ndi _______________ fomo to gbo ibawi  (a) eran (b) deko
 5. Ero ____________ ni gbogbo omo tii kobawi (a) eyin lawujo (b) iwaju nita

ITUWA IMOORESI ORI RE

 1. ____________________ dori kodo (a) Owiwi     (b) Adan
 2. O nwose ___________________ (a) Eye     (b) Eran
 3. E toju awon __________________ (a) ore     (b) obi
 4. Eyin ______________________ gbogbo (a) agba     (b) omode
 5. ___________ yii ko to rara (a) iwa (b) oro  

APA KETA
 1. Kini Ade nse ni ojoojumo  (a) o nfo eyin re     (b) o nfo ese re
 2. Bawo ni aso Ade se maa nri ni gbogbo igba  (a) o ndo ti     (b) o mo nini
 3. Eeri ara a maa fa _________________ (a) iku      (b) aisan
 4. Yera funwa ________________ patapata (a) Ika     (b) Obun
 5. Ki ______________ ma si le gbe o de   (a) obun    (b) aisan

ITOJU ILE
 1. Ayika ___________ to doti a maa fa aisan (a) ile (b) ara
 2. ________ kii se ore eniyan      (a) iya    (b) obun
 3. Ka ma gba __________ laaye      (a) egbin     (b) ika
 4. ____________ nii wo aso ___________       (a) ina, onida     (b) ojo, agbra
 5. Arun iwosi tinu _________ la wa       (a) idoti      (b) egbin
ISLAND BUILDERS BAPTIST SCHOOL
(NURSERY & PRIMARY)
15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.

FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 4                      SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………...

ASIMU OLE
 1. ______________ ni oruko oja ilu pokii    (a) ikilo     (b) oroorun     (d) ayelu
 2. Ohun ti ose akoba fun pokii ni pe _____________
(a) o ni ore pupo     (b) o nra epa je     (d) o nlo si oja ayelu
 1. Eni ti o bu Pokii pe “Lanboroki”, oju re jaa na ni __________
(a)    Ala dugbo Pokii kan    (b) ore Pokii kan        (d) obi Pokii
 1. _______________ ni eni ti won fa omo ti o jale gan an fun lati da seria fun-un
(a) olopaa         (b) Pokii     (d) ore Pokii
 1. Kini oruko Aladugbo Pokii ti omu-un pada sile ___________ (a) Akanni (b) Alao

OUNJE KARI AYE
 1. Eni ti o so pe paki ni wonfi nyan gaari ni    (a) Bunmi (b) Wale (d) Baba
 2. Ewo ni a nfi paki se ninu awon nnkan wonyii (a) kango (b) fufu (d) kokoro
 3. Bi agbado ba parade, a maa di ______    (a) ogi (b) fufu (d) lafun
 4. Ewo ni kii se ooto
(a) igi ege ni a maa ngbin (b) ilaje lo ni pupuru (d) agbado ni a fin se fufu
 1. Ko meji ninu ounje ti a maa nfi agbado se
(a) ________________________________      (b) ________________________________

ADUBI ATI IYA RE
 1. Omo meloo ni iya Adunbi bi? (a) meji     (b) meta     (d) ikan
 2. Iru  owo wo ni Awele nse (a) onta eja     (b) onta isu     (d) o ngba aaru
 3. Ona wo ni Olorun fi pon Adubi le?     (a) Adubi gbe odo oyinbo oniwaasu
(b) Adubi ba iya re ta eja        (d) Adubi lo yunifasiti Ibadan
 1. Kini o gbe Adubi de odo oyinbo oniwaasu
(a) O fe kawesi      (b) Ise omo odo    (d) ko mo eniyan kankan
 1. Kini koje ki Awele le paro aso bi awon elegbe re
(a) Ere oja re kop o    (b) Aso won ni ilu won    (d) o ya obun pupo

AWON ILU ORISIRISI
 1. Awon ___________ loni ilu bata  (a) onisango (b) elesu (d) oloya
 2. Awon ____________ loni ilu ipese  (a) Babalawo  (b) ologun  (d) elesu
 3. Awon ___________ loni ilu Agere (a) onifa (b) olobatala (d) ologun  
 4. Awon ____________ loni ilu igbin (a) olobatala (b) elegun (d) onisango  
 5. Awon ___________ loni ilu gbedu (a) alawo (b) oba ati ijoye (d) onigbagbo
ISLAND BUILDERS BAPTIST SCHOOL
(NURSERY & PRIMARY)
15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.

FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 5                      SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………...

ERE AYO
 1. Yoruba maa nse ere idaraya ni ____________ (a) osan (b) owuro (d) irole
 2. Omo ayo melo ni o ngbe oju opon
(a) merinlelogun     (b) mejidinladota     (d) marundinlogbon
 1. Apa ____________ ni a ma anta ayo si (a) otun (b) osi (d) eyin
 2. Omo ayo melo ni o maa nwa ninu iho Kankan (a) mejo (b) mefa (d) merin
 3. Oruko miran wo ni a lepe awon ti o nworan nidi ere ayo
(a) onilaja ayo        (b) osefe ayo    (d) olofofo ayo
ERE ARIN  
 1. Awon wo la le ba nidi ere arin tita (a) gende (b) agbalagba (d) omo wewe
 2. Kini eso arin fi awo jo (a) oronbo (b) paanu to dogun-un (d) opon
 3. Ona meji ti a le fit a arin ni _______     (a) ori ila ati inu ape arin
(b) inu opon ayo ati ori ila         (d) ori eni arin ati inu iho alatako
 1. Eso wo ni a le fidipo eso arin (a) osan mimu     (b) eyin    (d) oronbo wewe
 2. Ibo la tin se ere arin (a) ori pakiti     (b) ita gbangba    (d) ori opon
AKANLO EDE :
 1. Kini itumo akanloede yii:  ra owo si (a) bebe (b) seka (d) laja
 2. Fi aake kori: (a) salo (b) ko jale (d) fi aakesi ori
 3. Kini itumo akanlo ede yii: Fi imu finle (a) se iwadi oro (b) se ofofo (d) se ika
 4. Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo
(a) ko si atunse mo     (b) ko si ija mo     (d) ko si iya mo
 1. Kini itumo akanlo ede yii : Fomo yo (a) se aseyori (b) se wahala (d) se alaye
OWE ILE YORUBA: Pari awon owe wonyii
 1. Agba kii nwa loja _____________________________________________________
 2. Bami na omo mi ______________________________________________________
 3. Esin iwaju, __________________________________________________________
 4. Adan dori kodo, ______________________________________________________
 5. Ile la now, __________________________________________________________
ISLAND BUILDERS BAPTIST SCHOOL
(NURSERY & PRIMARY)
15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.

FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 6                      SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:………………………………………………………………………………...

ONKA NI EDE YORUBA  
 1. Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 75  
(a) arundinlogorin (b) arundinlogbon (d) arundinladota
 1. Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 95:
(a) arundinlogoje (b) arundinlogorun (d) arundinnigba
 1. Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 100: (a) adota (b) ogorin (d) ogorun
 2. Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 110: (a) adofa (b) adoje (d) ogoje
 3. Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 140: (a) ogorun (b) ogota (d) ogoje

AKAYE: IJAKO LERE
 1. Kini Ajao fese nigba ti Alagba Alao pariwo pe, “omo naa niyi”?
(a) o fe ba ehoro sare        (b) o fe salo         (d) o fe fun won ni ehoro
 1. Won ko patie bo o, “tumo si pe”    
(a) won na-an daadaa        (b) won je e niya     (d) won jaa ni patie
 1. Inu Alagba Alao dun nitori won _____     (a) bu Ajao    (b) na Ajao    (d) ko won jade
 2. ______ ti Alagba Alao lo ni o je ki won ri Ajao    (a) ile-eko    (b) ogba    (d) ita
 3. Oga ile-eko se ileri fun Alagba Alao pe oun yoo ____   
(a) dojuti won    (b) sare pea won obi (d) ba gbogbo awon ake koo soro   

EWI: OMOLUABI
 1. Ninu ewi yii, a rii pe, omoluabi maa n _____    (a) siwahu    (b) soyaya   (d) fewo
 2. Ewi yii ko nipe, omoluabi a maa ______
(a) sepe     (b) woso ti ko mo     (d) jeun ni won-tonwon si
 1. Omo ti yoo je asa mu tumo si  _____   
(a) omo ti yoo je ologbon   (b) oruko re yoo maa je Asamu  (d) yoo sa nnkan mu
 1. Akewi yii fe ki a je ________    (a) omoluabi     (b) gbewiri  (d) ole    
 2. Ewi yii so pe:- “a-la-jewo ra ni _______    (a) gbewiri  (b) obun (d) wobiaEWI: EKE KO NIGBONGBO
 1. Ewi yii je ewi ti o nkoni ni _______ (a) ogbon (b) iberu (d) ife
 2. Ewi yii nkilo pe, ki a mase ________ (a) korira (b) sole (d) puro
 3. Ewi yii so pe otito (a) lagbara (b) buru (d) ko ni gbongbo
 4. Ibi ti won fe ki omo fi ogbon naa pamo si ni ____ (a) owo otun (b) inu aso (d) owo osi
 5. Gbogbo nnka wonyii ni akewi ni ki a beru, afi ______ (a) iku (b) otito (d) arun

Subscribe to receive free email updates:

0 Response to "1st Term Examination Yoruba 2018 /2019 Academic Year "

Post a Comment