FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:...

FI LETA TI OYE DI AWON ALAFO WONYII
A ________ D ________ Ę ________ G _________
H _________ J ________ L ________ N _________
Ǫ ________ R ________ Ș ________ U _________ Y

DI AWON ALAFO WONYII PELU LETA TI O YE 
A d ____ (e , p)
E ____ e (k , w)
____ j a (E , M)
I g ____ (s , o)
O ____ o (K , T)
KINI ORUKO AWON AWORAN WONYII:
(Ade, Ile)

(Ododo, Ewe)
(Eja, Akan)
(Garawa, Igo)
(Owo, Ade)


MELO NIL ETA EDE YORUBA
Melo nil eta ede Yoruba lapapo (a) marundinlogbon (b) mejidinlogun
Melo ni iro faweli airanmupe ede Yoruba (a) mewa (b) meje
Melo ni iro faweli aranmupe ede Yoruba (a) marun-un (b) mejo
Melo ni awon konsonanti ede Yoruba (a) mejila (b) mejidinlogun
Ewo ni konsonanti aranmupe ninu awon wonyii (a) p (b) n (c) s