FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE


FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:...

FI LETA TI OYE DI AWON ALAFO WONYII 
A ________ D ________ Ę ________ G _________
H _________ J ________ L ________ N _________
Ǫ ________ R ________ Ș ________ U _________ Y 

DI AWON ALAFO WONYII PELU LETA TI O YE  
A d ____ (e , p)
 E ____ e (k , w)
____ j a (E , M)
I g ____ (s , o)
O ____ o (K , T)
KINI ORUKO AWON AWORAN WONYII:
     (Ade, Ile)

     (Ododo, Ewe)     (Eja, Akan)     (Garawa, Igo)
     (Owo, Ade)MELO NIL ETA EDE YORUBA
Melo nil eta ede Yoruba lapapo (a) marundinlogbon (b) mejidinlogun 
Melo ni iro faweli airanmupe ede Yoruba (a) mewa (b) meje
Melo ni iro faweli aranmupe ede Yoruba (a) marun-un (b) mejo
Melo ni awon konsonanti ede Yoruba (a) mejila (b) mejidinlogun 
Ewo ni konsonanti aranmupe ninu awon wonyii (a) p (b) n (c) s FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:...

ORIN AKOMONIWA: OMO RERE 
Omo rere kii ___________ (a) puro (b) sore
Omo rere kii ___________ (a) sun (b) sole
Omo rere kii ___________ (a) jale (b) woso
Omo rere kii ___________ (a) ponmi (b) seke
Omo rere kii ___________ (a) ja (b) gbadura

IWA OMOLUABI: ITOJU ATI OORE SISE
1.) _________ nse baba Aina (a) aisan (b) arun
2.) ____________ wa kii. (a) Yemi (b) Aina
3.) ___________________ fee ro (a) ojo (b) omi  
4.) Iya _________________________ sa awon aso re si ita (a) Kola (b) Ade
5.) ________________ nba ka awon aso naa (a) Yemi (b) Tola

IROYIN ATI ASOGBA
Ile-eko mi dara, tani o nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba
Bee ni, sugbon ko dara to ile-eko ti wa, tani o nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde
Wo o bi ododo se po yi kilaasi mi ka, tani o nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba
Igi ti o lewa po ni ile-eko temi ju tire lo, tani o nsoro yii (a) Tunde (b) Alaba
Wo maluu ti baba mi ra, tani o nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde

AROFO IMOTOTO
Fo ______________ re bi o baji (a) eyin (b) ese 
Gba __________________ re pelu (a) ori (b) ayika 
Ge _______________ re lasiko to ye (a) irun (b) imu
______________ ti ngbe abe eekannaa ko kere (a) aisan (b) arun
____________ buburu jinna si o tefe (a) arun (b) kaisanFIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:...

EWI: IBAWI 
Arofo yii nba omo ________________ wi (a) ile-eko (b) ile-ise 
__________ to gbo baa wi ni deni _________ leyin ola (a) omo giga (b) aya rere
Omo to gbo ____________ nii fi __________ sese rin (a) aya keke (b) omo moto
Eko ndi _______________ fomo to gbo ibawi (a) eran (b) deko 
Ero ____________ ni gbogbo omo tii kobawi (a) eyin lawujo (b) iwaju nita

ITUWA IMOORESI ORI RE

____________________ dori kodo (a) Owiwi (b) Adan
O nwose ___________________ (a) Eye (b) Eran
E toju awon __________________ (a) ore (b) obi
Eyin ______________________ gbogbo (a) agba (b) omode
___________ yii ko to rara (a) iwa (b) oro  

APA KETA 
Kini Ade nse ni ojoojumo (a) o nfo eyin re (b) o nfo ese re 
Bawo ni aso Ade se maa nri ni gbogbo igba (a) o ndo ti (b) o mo nini
Eeri ara a maa fa _________________ (a) iku (b) aisan
Yera funwa ________________ patapata (a) Ika (b) Obun 
Ki ______________ ma si le gbe o de (a) obun (b) aisan

ITOJU ILE 
Ayika ___________ to doti a maa fa aisan (a) ile (b) ara 
________ kii se ore eniyan (a) iya (b) obun
Ka ma gba __________ laaye (a) egbin (b) ika
____________ nii wo aso ___________ (a) ina, onida (b) ojo, agbra 
Arun iwosi tinu _________ la wa (a) idoti (b) egbin 

NAME:...

ASIMU OLE
______________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) oroorun (d) ayelu 
Ohun ti ose akoba fun pokii ni pe _____________ 
(a) o ni ore pupo (b) o nra epa je (d) o nlo si oja ayelu 
Eni ti o bu Pokii pe Lanboroki, oju re jaa na ni __________ 
(a) Ala dugbo Pokii kan (b) ore Pokii kan (d) obi Pokii
_______________ ni eni ti won fa omo ti o jale gan an fun lati da seria fun-un 
(a) olopaa (b) Pokii (d) ore Pokii 
Kini oruko Aladugbo Pokii ti omu-un pada sile ___________ (a) Akanni (b) Alao 

OUNJE KARI AYE 
Eni ti o so pe paki ni wonfi nyan gaari ni (a) Bunmi (b) Wale (d) Baba
Ewo ni a nfi paki se ninu awon nnkan wonyii (a) kango (b) fufu (d) kokoro
Bi agbado ba parade, a maa di ______ (a) ogi (b) fufu (d) lafun 
Ewo ni kii se ooto 
(a) igi ege ni a maa ngbin (b) ilaje lo ni pupuru (d) agbado ni a fin se fufu 
Ko meji ninu ounje ti a maa nfi agbado se 
(a) ________________________________ (b) ________________________________

ADUBI ATI IYA RE 
Omo meloo ni iya Adunbi bi? (a) meji (b) meta (d) ikan
Iru owo wo ni Awele nse (a) onta eja (b) onta isu (d) o ngba aaru 
Ona wo ni Olorun fi pon Adubi le? (a) Adubi gbe odo oyinbo oniwaasu 
(b) Adubi ba iya re ta eja (d) Adubi lo yunifasiti Ibadan
Kini o gbe Adubi de odo oyinbo oniwaasu 
(a) O fe kawesi (b) Ise omo odo (d) ko mo eniyan kankan 
Kini koje ki Awele le paro aso bi awon elegbe re 
(a) Ere oja re kop o (b) Aso won ni ilu won (d) o ya obun pupo 

AWON ILU ORISIRISI
Awon ___________ loni ilu bata (a) onisango (b) elesu (d) oloya
Awon ____________ loni ilu ipese (a) Babalawo (b) ologun (d) elesu 
Awon ___________ loni ilu Agere (a) onifa (b) olobatala (d) ologun  
Awon ____________ loni ilu igbin (a) olobatala (b) elegun (d) onisango  
Awon ___________ loni ilu gbedu (a) alawo (b) oba ati ijoye (d) onigbagbo FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:...

ERE AYO 
Yoruba maa nse ere idaraya ni ____________ (a) osan (b) owuro (d) irole 
Omo ayo melo ni o ngbe oju opon 
(a) merinlelogun (b) mejidinladota (d) marundinlogbon 
Apa ____________ ni a ma anta ayo si (a) otun (b) osi (d) eyin 
Omo ayo melo ni o maa nwa ninu iho Kankan (a) mejo (b) mefa (d) merin 
Oruko miran wo ni a lepe awon ti o nworan nidi ere ayo 
(a) onilaja ayo (b) osefe ayo (d) olofofo ayo 
ERE ARIN  
Awon wo la le ba nidi ere arin tita (a) gende (b) agbalagba (d) omo wewe 
Kini eso arin fi awo jo (a) oronbo (b) paanu to dogun-un (d) opon 
Ona meji ti a le fit a arin ni _______ (a) ori ila ati inu ape arin 
(b) inu opon ayo ati ori ila (d) ori eni arin ati inu iho alatako 
Eso wo ni a le fidipo eso arin (a) osan mimu (b) eyin (d) oronbo wewe 
Ibo la tin se ere arin (a) ori pakiti (b) ita gbangba (d) ori opon 
AKANLO EDE :
Kini itumo akanloede yii: ra owo si (a) bebe (b) seka (d) laja 
Fi aake kori: (a) salo (b) ko jale (d) fi aakesi ori 
Kini itumo akanlo ede yii: Fi imu finle (a) se iwadi oro (b) se ofofo (d) se ika 
Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo 
(a) ko si atunse mo (b) ko si ija mo (d) ko si iya mo 
Kini itumo akanlo ede yii : Fomo yo (a) se aseyori (b) se wahala (d) se alaye 
OWE ILE YORUBA: Pari awon owe wonyii 
Agba kii nwa loja _____________________________________________________
Bami na omo mi ______________________________________________________
Esin iwaju, __________________________________________________________
Adan dori kodo, ______________________________________________________
Ile la now, __________________________________________________________FIRST TERM EXAMINATION 2018/2019
CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:...

ONKA NI EDE YORUBA  
Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 75  
(a) arundinlogorin (b) arundinlogbon (d) arundinladota 
Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 95:
(a) arundinlogoje (b) arundinlogorun (d) arundinnigba 
Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 100: (a) adota (b) ogorin (d) ogorun 
Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 110: (a) adofa (b) adoje (d) ogoje 
Kini a npe nomba yii ni ede Yoruba 140: (a) ogorun (b) ogota (d) ogoje 

AKAYE: IJAKO LERE 
Kini Ajao fese nigba ti Alagba Alao pariwo pe, omo naa niyi? 
(a) o fe ba ehoro sare (b) o fe salo (d) o fe fun won ni ehoro
Won ko patie bo o, tumo si pe  
(a) won na-an daadaa (b) won je e niya (d) won jaa ni patie 
Inu Alagba Alao dun nitori won _____ (a) bu Ajao (b) na Ajao (d) ko won jade
______ ti Alagba Alao lo ni o je ki won ri Ajao (a) ile-eko (b) ogba (d) ita
Oga ile-eko se ileri fun Alagba Alao pe oun yoo ____ 
(a) dojuti won (b) sare pea won obi (d) ba gbogbo awon ake koo soro 

EWI: OMOLUABI 
Ninu ewi yii, a rii pe, omoluabi maa n _____ (a) siwahu (b) soyaya (d) fewo
Ewi yii ko nipe, omoluabi a maa ______ 
(a) sepe (b) woso ti ko mo (d) jeun ni won-tonwon si
Omo ti yoo je asa mu tumo si _____ 
(a) omo ti yoo je ologbon (b) oruko re yoo maa je Asamu (d) yoo sa nnkan mu 
Akewi yii fe ki a je ________ (a) omoluabi (b) gbewiri (d) ole  
Ewi yii so pe:- "a-la-jewo ra ni _______ (a) gbewiri (b) obun (d) wobiaEWI: EKE KO NIGBONGBO
Ewi yii je ewi ti o nkoni ni _______ (a) ogbon (b) iberu (d) ife 
Ewi yii nkilo pe, ki a mase ________ (a) korira (b) sole (d) puro 
Ewi yii so pe otito (a) lagbara (b) buru (d) ko ni gbongbo 
Ibi ti won fe ki omo fi ogbon naa pamo si ni ____ (a) owo otun (b) inu aso (d) owo osi 
Gbogbo nnka wonyii ni akewi ni ki a beru, afi ______ (a) iku (b) otito (d) arun 

No comments