Bí a ṣe nki àwọn onírúurú osise ni ile Yorùbá

BI A SE NKI AWON ONIRUNRU OSISE NI ILE YORUBA

Alagbede – Aroye ooooAgbe – Arokobodunde

Akope – Igaba a ro o

Onidiri – Oju gbooro/E ku ewa

Onisowo – aje a wo gba o

Alaro – Aredu/Arepa

Olode – Arinpa Ogun ó, ogún a fowo jonaa oooAwako – Awaye o, oko a re fo o

Babalawo – Aboruboye ni le Ifa

Onise Oluwa Alufaa/wolii – Eku ise oluwa,

Oluwa yio so agbara do'tun o

Oni lu – Aluye

Oloyun – Asokale anfaani o, afon a gbo ki o to wo

Awako èrò - àwa yee ooo

Àpẹẹrẹ àwọn ìdáhùn sí àwọn ikinni wonyi

ORISIRISI ISE NI ILE YORUBA

Ìṣe Ìkíni. IDAHUN

Agbe. Aroko bodunde o Ase o

Akope Igba a ro o Ogun a gbe o o

Ode Aripa ogun ó. Ase o, ogun a gbe o o

Alaro Aredu o Iyamopo a gbe o o

Alagbede Aroye o Ase o, ogun a gbe o o

Ahunso. Ahun ya o Oko tabi apasa ni yoo mi lati dahun

Gbenagbena Asogun aro o Akoko

Onidiri. Oju gbooro o Ooya a ya o

Amokoko Amoye o Iyamopo a gbe o oBabalawo Aboruboye o Aboye bo sise nile ifa o

Apeja Adepa o Ase o

Awako Awaye o Ase o

Oníṣòwò. Aje a wogba ó. Ase o

No comments