Followers

Follow by Email

Asegbolu Matched Content

Join us on Facebook

Naija we hail oooo Una no dey fail oooo even when the country they wail lli oooo

Powered by Blogger.
Related Posts Plugin for WordPress, Blogger...

Lagos State Approved School Calender For 2019/2020 Academic Calendar.

1st term resumption date is on 9th September ,2019.
1st mid term break is on 28rh October to 1st November 2019
1st Term Vacation is on 16th December 2019 

Now Your can do these at home and help yourself

FOUR THINGS YOU CAN NOW DO BY YOURSELF WITHOUT ANY MIDDLE MEN IN NIGERIA

Many years ago, you would spend tons of Naira and wait for months to get some of these things done. Even with man-know-man, some of these important documents could take weeks and a lot of extra-extra-express cash and plenty abeg.

Let's go there!!

1. COMPANY REGISTRATION
You can now register your business with CAC officially online and go collect your Certificate in a few days. You can start by going to
http://new.cac.gov.ng/home/ and following through.

2. INTERNATIONAL PASSPORT
You can now complete your forms and even make payments for your international passports from many country in the world. After you obtain your confirmation of payment(online), you can head to any immigration office or Nigerian embassy abroad and do your biometric capture. You will be notified when to come and collect your passport. All these without any middle men or special connections. Go to 

3. NATIONAL IDENTITY CARD
You can do your pre-enrollment online, print out your acknowledgement and go to any NIMC office and do your boimetric capture. You will be issued with a NIN(National Identification Number) instantly and a print-out that you can use in any transaction that requires a personal identification. You will also be notified later when the physical National ID card is ready for Pick-up. Go to https://www.nimc.gov.ng/ to start this process.


4. DRIVERS LICENCE
You can now renew your drivers licence online. Go to the link below and follow the in instructions, pay online, print your acknowledgement and you will be notified when to come pick up the physical licence. You can use the acknowledgement any time your licence if required by any authority up until your licence is ready for pick up. Go to https://www.nigeriadriverslicence.org/  to commence the renewal process.

Hope this was of value to you. We will be updating you with more resources you can take advantage of to make life easier in Nigeria.


YORUBA LANGUAGE PRIMARY 6


PRIMARY 6                                                 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON
1.)   Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji            (b) meta         (d) okan         (e) merin
2.)   Kini ise awon omo wonyii (a) agbe     (b) ode          (d) ademu      (e) akekoo
3.)   Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye       (b) Emo          (d) Adan    (e) Alangba
4.)   Kini o mu ki won re roba Dauda? (a) o fin pa eye                (b) o fin pa adan
(d) koje ki o koju si eko re       (e) o fi fo agbe emu
5.)   Kini Dauda fi ile agbon pe? (a) ile-eye          (b) ile-eku     (d) adan         (e) agbe-emu

IWE KIKA: - LAMURIN YA WERE
1.)   Iru eniyan wo ni baba Lamurin (a) oba          (b) olowo      (d) talaka       (e) ode
2.)   Ojo wo ni isele yii waye ganan (a) ojo ose    (b) ojo odun  (d) ojo oja     (e) ojo ere
3.)   Kini Lamurin lose ni oko ni ojo naa
(a) o lo wa igi      (b) o lo he ekuro       (d) o lo sa obi            (e) o lo wa isu
4.)   Kini o mu inu bi Lamurin
(a) ko gbadun iwe naa   (b) o ri ewu re lorun elomiran  (d) omi odo ko kaa lara  (e) orun wo o 
5.)   Kini awon ero oja fi na lamurin (a) ada          (b) kumo        (d) opa           (e) owo

IWE KIKA: - WARA
1.)   Awon wo lo nse wara (a) maluu (b) Fulani (d) bomubomu (e) kolobo
2.)   Ni akoko wo ni won maa nbere ise wara sise (a) osan (b) iyale ta (d) owuro (e) oyanjo
3.)   Ara eranko wo ni won ti nri wara (a) agbo (b) opije (d) ako maluu (e) abo maluu
4.)   Iru ewe wo ni won fin se wara (a) ewe ope (b) ewe odan (d) ewe ibepe (e) ewe bomubomu
5.)   Ounje miran ti a maa nsebi wara ni _____ (a) isu (b) eko (d) oka (e) eba

IKINI LENU ISE ATI IDAHUN
S/N
Onise
Ikini
Idahun
1.)
Alagbede


2.)
Akope


3.)
Babalawo


4.)
Alaro


5.)
Onidiri


6.)
Awako


7.)
Onisowo


8.)
Alayo


9.)
Ode


10.)
Amokoko
YORUBA LANGUAGE PRIMARY 5 SECOND TERM EXAMINATION

SECOND TERM EXAMINATION 2019

CLASS: PRIMARY 5                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

1.)   Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije

 

2.)   Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won

IWE KIKA DAROSA

1.)   Kini so darosa di olokiki? (a) ile ti o ko    (b) egbe ti o nko   (d) eko ti o ko (e) owo ti o ni

2.)   Ona wo ni darosa ngba ran mekunnu lowo

(a) o nya won lowo     (b) o nran won nile eko   (d) o nfun won ni ise se (e) o nya won nile gbe  

3.)   Iru iranlowo wo ni darosa nse fun awon akekoo?  (a) o nraso ile-eko fun won     

(b) o nfun won ni eko-ofe    (d) o nra aso odun funwon  (e) o nfun won ni ebun owo

 

4.)   Nibo ni darosa ti nri owo tire?

(a) nibi ole jija    (b) nibi jibiti lilu    (d) nibi iranlowo (e) nibi ile-ise re

5.)   Darosa nfe ki omode ______

(a) feran obi    (b) maa sa ni ile-eko  (d) fi oju si eko re  (e) di fole fole

 

OWE ILE YORUBA  

1.)   Pari owe yii: Agba kii nwa loja __________________________________________________

2.)   Bami na omo mi, _____________________________________________________________

3.)   Ile ti a fi ito mo ______________________________________________________________

4.)   Esin iwaju, __________________________________________________________________

5.)   Obe ti baale ile kii nje, _________________________________________________________


YORUBA LANGUAGE PRIMARY 4

: PRIMARY 4                                                          SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ORIKI ILU

1.)   Ilu wo ni a nki bayii pe, mesi ogo, nile oluyole, nibi ole gbe njare onihun

(a) Ibadan   (b) Akura  (d) Oyo

2.)   Ilu wo ni a nki bayi pe, akete ile ogbon, aromisa legbe legbe (a) Egba  (b) Eko    (d) Akure

3.)   Ilu wo ni a nki bayi pe: oloyemekun, omo a muda sile mogun enu pani

(a) Akure    (b) Ilorin (d) Ondo

4.)   Ilu wo ni a nki bayi pe; omo ajifi kalamu damo leko arise kandun kandun, ilu to jinna to sunmo alujona (a) Egba (b) Oyo (d) Ilorin

 

5.)   Ilu wo ni a nki bayii pe, omo lisabi, oniruuru – po nile Alake (a) Ogbomoso (b) Egba (d) Ijesa

 

ONKA NI EDE YORUBA

1.)   Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 75

(a) arundinlogbon (b) arundinlogoji (d) arundinlogorun

2.)   Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 45

(a) arundinladota (b) arundinlogun (d) arundinlogorun

3.)   Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 90 (a) ogorun (b) adorun (d) ogota

4.)   Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) ogorin (b) ogorun (d) adofa

5.)   Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 65

(a) arundinladorin (b) arundinlogoji (d) arundinnigba

 

ASO ILE YORUBA

1.)   Ewo ni aso ile wa ninu awon oruko wonyii (a) alari (b) akara (d) seti

2.)   Ara ti obinrin fi aso ran ni _____ ati _____

(a) gele ati ipele (b) iro ati buba (d) oyala ati dansiki

3.)   Ara to okunrin nfi aso ran ni ______ ati _____

(a) buba ati sokoto (b) iro ati gele (d) tobi ati oyala

4.)   Aso ati a nran ti o ngun de orun ese ni ______ o dabi jalamia ti won ba ran tan

(a) agbada (b) dandogo (d) gbariye

5.)   Aso ti o jo agbada, sugbon ko tobi to agbada ti a ba ran tan ni a npe ni _____

(a) dansiki (b) gbariye (d) oya

 

 

 

 

 

AGBON TA GBONJU

1.)   Kini o ta gbonju? (a) ikamudu    (b) oyin    (d) agbon          (e) kan-in-kan-in

2.)   Ninu eko yii, baba gbonju ko fe ki awon omo oun ya______

(a) ole   (b) ole    (d) olojukokoro (e) alaigboran

3.)   Itumo se imele ni ______ (a) roju      (b) gun ope     (d) ja ole    (e) ya ole

4.)   __________ ni baba gbonju (a) olowo    (b) akikanju    (d) ole     (e) okuroro

5.)   Kini koje ki baba gbonju lo si oko (a) idiwo kekere (b) ise nla   (d) oro aje   (e)

 

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 2

: PRIMARY 2                                                          SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ERE AYO

1.)  ________ ni igi gbooro gidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo         (b) awo ayo

2.)  Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo     (b) merin

3.)  Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun          (b) osi

4.)  Enikan _________ ni o nta ayo olopon leekan naa (a) merin    (b) meji

5.)  Omo ayo ______ ni o ngbe ni oju opon ayo lapapo (a) mejidinladota (b) merinlelogun

 

ALO  APAMO

1.)  Alo o, alo o, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buruku tori bo, kini o

(a) irin    (b) omorogun

2.)  Alo o, alo o, opa tinrin kanle, o karun, kini o (a) ojo     (b) agbara

3.)  Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruko bi igba omo, gbogbo won lo le tiro, kini o   (a) ata   (b) ewa

 

4.)  Alo o, alo o, mo nlo soyo; mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o

(a) ilu     (b) igba

5.)  Alo o, alo o, aso baba mi kan laelae, aso baba mi kan laelae, eti lo ngbo, kii gbo laarin,  kini o  (a) agbara       (b) odo

 

ALO APAGBE: IJAPA  ATI  OKERE  

1.)  _________ ati okere  je ore   (a) asin        (b) ijapa

2.)  _______ kii  se ore won        (a) ijapa       (b) asin

3.)  Ijapa la ija ___________ (a) ogbon (b) eru

4.)  Ija sele laarin ________ ati ______ (a) ijapa ati asin (b) asin ati okere

5.)  Inu bii asin gidigidi, o sig e e je ni __________ (a) imu (b) ese  

 

IMOTOTO  ILE

1.)  _______ nge koriko ti o wa ni ayika ile (a) Tunde        (b) Kola

2.)  _________ ngba idoti ati panti inu ile sita   (a) Yemi   (b) Bola

3.)  Mama ________ sese fo aso tan ni   (a) Bola      (b) Kemi

4.)   Baba ________ naa fe sun panti ti won ti ko jo nina   (a) Kola        (b) Tunde

5.)  O n sa wonsi ori _________ isasosi (a) okun      (b) igi  

Description: IMG-20130905-WA0002ISLAND BUILDERS BAPTIST SCHOOL

(NURSERY & PRIMARY)

15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.

 

SECOND TERM EXAMINATION 2019

CLASS: PRIMARY 3                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

OTITO BORI  

1.)   Ilu wo ni itan yii ti sele _____ (a) Ayokooto      (b) Ayedande

2.)   Kii ni ise Mosun (a) agbejoro     (b) onisowo

3.)   Talo se ijanba fun Mosun? (a) Agbalagba kan   (b) Omodekunrin kan

4.)   Bawo ni won se ko ba Mosun?    (a) won ba Mosun ja        (b) won fi oja fayawo ranse si iso re  

5.)   Bawo ni Mosun se bo ninu isoro re? (a) awon olopaa fi sile     (b) omode kunrin kan lo tu asiri  

 

ALO APAMO  

1.)   Alo o, alo o, opo baba alo kan laelae, opo baba alo kan laelae, ojo to ba de fila pupa ni iku de ba a o, kini o  (a) abela      (b) omorogun  

 

2.)   Alo o, alo o, ikoko rugudu feyin tigbo, kini o (a) ijapa        (b) igbin

3.)   Alo o, alo o, kini koja niwaju oba ti ko ki oba, kini o (a) agbara    (b) sigidi

4.)   Alo o, alo o, awe obi kana je doyo, kini o    (a) enu                         (b) ahon

5.)   Alo o, alo o, yara kotopo, kiki egun, ki ni o  (a) enu     (b) ibepe

 

ALO APAGBE: IJAPA ATI ERIN

1.)   Kini awon oba fi maa nbo ori won laye atijo (a) eranko nla           (b) eranko wewe

2.)   Bawo ni ijapa se je si erin (a) ota        (b) ore

3.)   Ona wo ni ijapa gba mu erin wo ilu (a) o fun ni akara         (b) o fun ni robo aladun

4.)   Ileri wo ni kabiyesi se fun ijapa (a) o da ohun ini resi meji            (b) o je ijapa ni iya

5.)   Eko wo ni itan yii ko wa?

(a) okowa ki a maa sora ni ile aye       (b) o kowa ki a maa sora fun awon odale ore

 

SISE KANGO

1.)   Iya __________ fe din kango (a) Ayoka       (b) Adunni

2.)   ________ ya agbado wa lati oko (a) Egbon  (b) Baba

3.)   Iya Adunni re agbado naa sinu ______ nla kan  (a) ikoko  (b) agba

4.)   O bu epo pupa sinu _______ (a) ina (b) agbada

5.)   Nigba ti __________ gbona daadaa (a) epo (b) omi

 

About

Add Your Gadget Here

Entertainment

Latest News

Entertainment

Subscribe Via Email

Subscribe to our newsletter to get the latest updates to your inbox. ;-)

Your email address is safe with us!

(C) Copyright by Naija Google Blogger
Wordpress Theme by QualityWP | Conveted to Blogger Template by ThemeLib.com

Search This Blog

Pages

Total Pageviews

About Me

author
Learn More →

Search Box

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 4

: PRIMARY 4                                                          SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ...
Read More

YORUBA LANGUAGE PRIMARY 2

: PRIMARY 2                                                          SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ...
Read More